1 ÀWỌN ỌBA
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Dáfídì àti Ábíṣágì (1-4)
Ádóníjà wá ọ̀nà láti gorí ìtẹ́ (5-10)
Nátánì àti Bátí-ṣébà gbé ìgbésẹ̀ (11-27)
Dáfídì pàṣẹ pé kí wọ́n fòróró yan Sólómọ́nì (28-40)
Ádóníjà sá lọ sí ibi pẹpẹ (41-53)
2
Dáfídì fún Sólómọ́nì ní ìtọ́ni (1-9)
Dáfídì kú; Sólómọ́nì gorí ìtẹ́ (10-12)
Ọ̀tẹ̀ Ádóníjà yọrí sí ikú fún un (13-25)
Ọba lé Ábíátárì kúrò lẹ́nu iṣẹ́; ó pa Jóábù (26-35)
Wọ́n pa Ṣíméì (36-46)
3
Sólómọ́nì fẹ́ ọmọ Fáráò (1-3)
Jèhófà fara han Sólómọ́nì lójú àlá (4-15)
Sólómọ́nì dá ẹjọ́ láàárín àwọn ìyá méjì (16-28)
4
5
6
7
8
Wọ́n gbé Àpótí wọnú tẹ́ńpìlì (1-13)
Sólómọ́nì bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ (14-21)
Àdúrà tí Sólómọ́nì fi ya tẹ́ńpìlì sí mímọ́ (22-53)
Sólómọ́nì súre fún àwọn èèyàn náà (54-61)
Àwọn ẹbọ àti àjọyọ̀ ìyàsímímọ́ (62-66)
9
Jèhófà tún fara han Sólómọ́nì (1-9)
Ẹ̀bùn tí Sólómọ́nì fún Ọba Hírámù (10-14)
Oríṣiríṣi iṣẹ́ ìkọ́lé tí Sólómọ́nì ṣe (15-28)
10
11
Àwọn ìyàwó Sólómọ́nì yí i lọ́kàn pa dà (1-13)
Àwọn alátakò dìde sí Sólómọ́nì (14-25)
Ọlọ́run ṣèlérí ẹ̀yà mẹ́wàá fún Jèróbóámù (26-40)
Sólómọ́nì kú; wọ́n fi Rèhóbóámù jọba (41-43)
12
Ìdáhùn líle tí Rèhóbóámù fún àwọn èèyàn (1-15)
Ẹ̀yà mẹ́wàá yapa (16-19)
Wọ́n fi Jèróbóámù jẹ ọba Ísírẹ́lì (20)
Ọlọ́run ní kí Rèhóbóámù má ṣe bá Ísírẹ́lì jà (21-24)
Ìjọsìn ère ọmọ màlúù tí Jèróbóámù gbé kalẹ̀ (25-33)
13
14
15
Ábíjámù di ọba Júdà (1-8)
Ásà di ọba Júdà (9-24)
Nádábù di ọba Ísírẹ́lì (25-32)
Bááṣà di ọba Ísírẹ́lì (33, 34)
16
Ìdájọ́ Jèhófà lórí Bááṣà (1-7)
Élà di ọba Ísírẹ́lì (8-14)
Símírì di ọba Ísírẹ́lì (15-20)
Ómírì di ọba Ísírẹ́lì (21-28)
Áhábù di ọba Ísírẹ́lì (29-33)
Híélì tún Jẹ́ríkò kọ́ (34)
17
Wòlíì Èlíjà sọ tẹ́lẹ̀ pé ọ̀dá máa wà (1)
Àwọn ẹyẹ ìwò bọ́ Èlíjà (2-7)
Èlíjà dé sọ́dọ̀ opó kan ní Sáréfátì (8-16)
Ọmọ opó náà kú, ó sì jíǹde (17-24)
18
Èlíjà pàdé Ọbadáyà àti Áhábù (1-18)
Èlíjà àti àwọn wòlíì Báálì ní Kámẹ́lì (19-40)
Ọ̀dá ọlọ́dún mẹ́ta àti ààbọ̀ dópin (41-46)
19
Èlíjà sá lọ nítorí ìbínú Jésíbẹ́lì (1-8)
Jèhófà fara han Èlíjà ní Hórébù (9-14)
Ọlọ́run ní kí Èlíjà fòróró yan Hásáẹ́lì, Jéhù àti Èlíṣà (15-18)
Ọlọ́run yan Èlíṣà sí ipò Èlíjà (19-21)
20
Àwọn ará Síríà gbógun ti Áhábù (1-12)
Áhábù ṣẹ́gun àwọn ará Síríà (13-34)
Àsọtẹ́lẹ̀ lórí Áhábù (35-43)
21
Ọgbà àjàrà Nábótì wọ Áhábù lójú (1-4)
Jésíbẹ́lì fa ikú Nábótì (5-16)
Iṣẹ́ tí Èlíjà jẹ́ fún Áhábù (17-26)
Áhábù rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ (27-29)
22
Àjọṣe Jèhóṣáfátì àti Áhábù (1-12)
Mikáyà sọ tẹ́lẹ̀ pé wọ́n máa ṣẹ́gun Áhábù (13-28)
Wọ́n pa Áhábù ní Ramoti-gílíádì (29-40)
Jèhóṣáfátì ṣàkóso lórí Júdà (41-50)
Ahasáyà di ọba Ísírẹ́lì (51-53)