DÁNÍẸ́LÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Àwọn ará Bábílónì dó ti Jerúsálẹ́mù (1, 2)
Wọ́n dìídì dá àwọn ọmọ ọba tí wọ́n kó lẹ́rú lẹ́kọ̀ọ́ (3-5)
Wọ́n dán ìṣòtítọ́ àwọn Hébérù mẹ́rin wò (6-21)
2
Ọba Nebukadinésárì lá àlá tó bà á lẹ́rù (1-4)
Amòye kankan ò lè rọ́ àlá náà (5-13)
Dáníẹ́lì ní kí Ọlọ́run ran òun lọ́wọ́ (14-18)
Dáníẹ́lì yin Ọlọ́run torí pé Ó ṣí àṣírí náà payá (19-23)
Dáníẹ́lì rọ́ àlá náà fún ọba (24-35)
Ìtumọ̀ àlá náà (36-45)
Ọba dá Dáníẹ́lì lọ́lá (46-49)
3
Ère wúrà tí Ọba Nebukadinésárì ṣe (1-7)
Wọ́n fẹ̀sùn kan àwọn Hébérù mẹ́ta pé wọn ò ṣègbọràn (8-18)
Wọ́n jù wọ́n sínú iná ìléru (19-23)
Ọlọ́run gbà wọ́n sílẹ̀ nínú iná náà lọ́nà ìyanu (24-27)
Ọba gbé Ọlọ́run àwọn Hébérù ga (28-30)
4
Ọba Nebukadinésárì gbà pé Ọlọ́run ni ọba (1-3)
Ọba lá àlá nípa igi kan (4-18)
Dáníẹ́lì túmọ̀ àlá náà (19-27)
Ó kọ́kọ́ ṣẹ sí ọba lára (28-36)
Ọba gbé Ọlọ́run ọ̀run ga (37)
5
6
Àwọn ìjòyè ilẹ̀ Páṣíà gbìmọ̀ pọ̀ láti mú Dáníẹ́lì (1-9)
Dáníẹ́lì ò yéé gbàdúrà (10-15)
Wọ́n ju Dáníẹ́lì sínú ihò kìnnìún (16-24)
Ọba Dáríúsì bọlá fún Ọlọ́run Dáníẹ́lì (25-28)
7
Ìran àwọn ẹranko mẹ́rin (1-8)
Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé mú ìjókòó ní kọ́ọ̀tù (9-14)
A fi ìtumọ̀ han Dáníẹ́lì (15-28)
Ọba mẹ́rin ni àwọn ẹranko mẹ́rin náà (17)
Àwọn ẹni mímọ́ máa gba ìjọba (18)
Ìwo mẹ́wàá, tàbí ọba mẹ́wàá, máa dìde (24)
8
9
Dáníẹ́lì gbàdúrà ìjẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ (1-19)
Gébúrẹ́lì wá bá Dáníẹ́lì (20-23)
Àsọtẹ́lẹ̀ nípa àádọ́rin ọ̀sẹ̀ (24-27)
10
11
12