JÓNÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Jónà fẹ́ sá fún Jèhófà (1-3)
Jèhófà mú kí ìjì kan tó lágbára jà (4-6)
Jónà ló fa wàhálà tó dé bá wọn (7-13)
Wọ́n ju Jónà sínú òkun tó ń ru gùdù (14-16)
Ẹja ńlá kan gbé Jónà mì (17)
2
3
Jónà ṣègbọràn sí Ọlọ́run, ó sì lọ sí Nínéfè (1-4)
Ọ̀rọ̀ Jónà mú kí àwọn ará Nínéfè ronú pìwà dà (5-9)
Ọlọ́run pinnu pé òun ò ní pa Nínéfè run (10)
4