Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
February 8, 2001
Fífarada Kòókòó Jàn-ánjàn-án Òde Òní
Fún àwọn kan, kòókòó jàn-ánjàn-án ìgbésí ayé dà bíi pé ó túbọ̀ ń le sí i ni. Kí la lè ṣe láti fara dà á?
3 Kòókòó Jàn-ánjàn-án Ayé Yìí Pàpọ̀jù
5 Ohun Tó Ń Ṣẹlẹ̀ Nígbà Táa Bá Ṣe Ohun Tó Pọ̀ Jù
8 Fífayọ̀ Fara Dà Á Nínú Ayé Oníkòókòó Jàn-ánjàn-án Yìí
14 Ǹjẹ́ o Mọ̀?
15 Nígbà Tí Àrùn Burúkú Kan Bá Kọ Lù Ọ́
18 Báwo Lo Ṣe Lè Fara Da—Àmódi Tí Ń Ṣe Ọ́?
23 Kíkojú Ìfàsẹ́yìn Nípa Gbígbé Góńgó Kalẹ̀
30 Wíwo Ayé
32 “Ó Ń Fini Lọ́kàn Balẹ̀, Ó Tún Ń fún Ìgbàgbọ́ Lókun”
Ṣé Ó Yẹ Kí Ìgbéyàwó Wà Pẹ́ Títí? 12
Kí ni Bíbélì sọ nípa èyí?
Bí Àwọn Òbí Mi Bá Sọ Pé Mi Ò Tíì Tẹ́ni Ń Dájọ́ Àjọròde Ńkọ́? 27
Ṣe ewú ńbẹ nínú títètè bẹ̀rẹ̀ sí í dájọ́ àjọròde ni?