Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
March 08, 2003
Àìjẹunrekánú—“Àrùn Gbẹ̀mígbẹ̀mí Táráyé Ò Kọbi Ara Sí”
Kí nìdí tí ọ̀pọ̀ èèyàn, pàápàá jù lọ àwọn ọmọdé, kò fi ń rí oúnjẹ tó dára tó jẹ? Kà nípa àwọn ìṣòro ńlá tó ń fa àìjẹunrekánú àti bí a ṣe lè dènà rẹ̀.
5 Àwọn Ìṣòro Ńlá Tó Ń fà Á Àti Ibi Tí Àbájáde Rẹ̀ Nasẹ̀ Dé
10 “Àrùn Gbẹ̀mígbẹ̀mí Táráyé Ò Kọbi Ara Sí” Yìí Máa Tó Dópin!
16 Ìbẹ̀wò sí Ìlú Tí Wọ́n Ti Ń Wa Góòlù Dúdú
25 Ọkùnrin Kan Tó Yàn Láti Ṣègbọràn Sí Ọlọ́run
28 Aráàlú Ṣèbẹ̀wò Tó Mórí Wọn Wú
32 “Ìgbà Yìí Gan-an Ni Mo Ṣẹ̀ṣẹ̀ Wá Mọ Bó Ṣe Wúlò Tó”
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kí N Máa Wo Àwọn Fídíò Orin? 13
Ọ̀pọ̀ àwọn fídíò orin ló túbọ̀ ń kún fún ìwà ipá àti ìwà pálapàla. Ìpinnu wo lo máa ṣe?
Ohun Àgbàyanu Ni Ṣíṣílọ Àwọn Ẹranko Wildebeest 19
Ìran mánigbàgbé ni wíwo bí àìlóǹkà àwọn ẹranko wildebeest ṣe ń sáré kìtìkìtì nínú igbó ilẹ̀ Áfíríkà.
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 2]
Somalia
[Credit Line]
© Betty Press/Panos Pictures
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ẹ̀YÌN ÌWÉ: UN/DPI Photo by Eskinder Debebe