Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May 8, 2003
Ohun Tó O Lè Ṣe Tó O Bá ní Àrùn Àtọ̀gbẹ
Kí ló ń fa àrùn àtọ̀gbẹ? Kí làwọn tó ní àrùn náà lè ṣe nípa rẹ̀?
3 Àtọ̀gbẹ—“Àrùn Tó Ń Yọ́ Kẹ́lẹ́ Ṣọṣẹ́”
5 Àwọn Ìṣòro Tó Rọ̀ Mọ́ Títọ́jú Àrùn Àtọ̀gbẹ
12 Bí Bíbélì Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ fún Àwọn Tó Ní Àrùn Àtọ̀gbẹ
13 Àwọn Ọmọ Tí Kò Gbádùn Ìgbà Èwe Wọn
14 Ohun Tí Kì Í Jẹ́ Kí Àwọn Ọmọdé Gbádùn Ìgbà Èwe Wọn
18 Jíjẹ́ Kí Àwọn Ọmọdé Gbádùn Ìgbà Èwe Wọn
26 Kò Retí Pé Òun Á Ṣàṣeyọrí Tó Tóyẹn
28 Ẹ̀pà Èso Tí Kò Jọjú, àmọ́ Tó Wúlò fún Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Nǹkan
32 Ìmọ̀ràn Àtàtà fún Àwọn Ọ̀dọ́
Kí Nìdí Tí Wọ́n Fi Fi Mí Sọ́dọ̀ Alágbàtọ́? 21
Mímọ̀ pé ọmọ tí wọ́n gbà tọ́ ni ọ́ lè mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìrònú tí kò tọ̀nà wá sọ́kàn rẹ. Kọ́ nípa bó o ṣe lè fi àwọn ìrònú tó dára rọ́pò àwọn èrò tí kò tọ̀nà wọ̀nyí.
Ǹjẹ́ Ìṣọ̀kan Kristẹni Ń Béèrè Pé Kí Ìpinnu Àwọn Kristẹni Dọ́gba? 24
Ǹjẹ́ Bíbélì fún wa lómìnira láti ṣe àwọn ohun tó wù wá bí ẹnì kọ̀ọ̀kan?