Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
June 8, 2003
Kí Ló Ń ṣẹlẹ̀ Sí Àwọn Ìlànà Rere?
Ńṣe làwọn ìlànà ayé yìí ń yára yí padà tí wọ́n sì ń burú sí i. Ipa wo làwọn ìlànà tó ń yí padà wọ̀nyí ní lórí rẹ?
3 Ìdí Táwọn Ìlànà Fi Ń Yí Padà
4 Àwọn Ìlànà Rere Ń jó Àjórẹ̀yìn
7 Ìlànà Rere Tó Ń Jó Àjórẹ̀yìn Yìí Ipa Wo Ló Ń ní Lórí rẹ?
10 Ìjọba Kan Tí Yóò Rọ̀ Mọ́ Àwọn Ìlànà Ọlọ́run
12 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
13 Àwọn Àrùn Tí Kòkòrò Ń gbé Kiri Ìṣòro Tí Ń Gbilẹ̀
16 Kí Ló Dé Tí Wọ́n Tún Fi Ń Padà Wá?
21 Ǹjẹ́ Ipò Nǹkan Lè Dára Sí I?
23 Omi Ohun Iyebíye Tó Ń Mú Ká Wà Láàyè
Yẹra fún Sísọ Ọ̀rọ̀ Tó Máa Ń Dunni 26
Kí ni Bíbélì sọ nípa irú ọ̀rọ̀ tó yẹ ká máa sọ sí àwọn ẹlòmíràn?
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Kojú Ìṣòro Jíjẹ́ Ọmọ Àgbàtọ́? 29
Kà nípa bí ọ̀dọ́ kan ṣe lè kojú ìṣòro jíjẹ́ ọmọ àgbàtọ́ tí yóò sì ṣàṣeyọrí.