Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November 8, 2003
Epo Rọ̀bì—Ṣé Wọ́n Lè Wà Á Gbẹ?
Kí ló mú kí epo rọ̀bì ṣe pàtàkì tó bẹ́ẹ̀ nínú ìgbésí ayé òde òní? Báwo la ṣe ń rí i? Báwo ni epo rọ̀bì tó ṣẹ́ kù láyé ṣe pọ̀ tó? Ǹjẹ́ àwọn nǹkan mìíràn wà tá a lè lò láti fi rọ́pò rẹ̀?
3 Epo Rọ̀bì—Bí Ó Ṣe Wúlò fún Ọ
4 Epo Rọ̀bì—Báwo La Ṣe Ń Rí I?
11 Epo Rọ̀bì—Ṣé Ìbùkún òun Ègún Ni?
12 Epo Rọ̀bì—Ṣé Wọ́n Lè Wà Á Gbẹ?
20 Ṣíṣèrànwọ́ Nígbà Ìṣẹ̀lẹ̀ Omíyalé Ní Àgbègbè Caucasus
30 Wíwo Ayé
32 ‘Ìwé Ìròyìn Tó Yẹ Kéèyàn Fara Balẹ̀ Kà Ni’
Ìdí Tí Orúkọ Jèhófà Fi Gbajúmọ̀ ní Erékùṣù Pàsífíìkì 16
Àwọn èèyàn lo orúkọ Ọlọ́run, Jèhófà, gan-an ní erékùṣù Pàsífíìkì ní ọgọ́sàn-án ọdún sẹ́yìn. Wàá gbádùn ìtàn yìí lọ́pọ̀lọpọ̀.
Ohun Tó Mú Kí Ìgbésí Ayé Mi Nítumọ̀ 23
Kà nípa ìdálẹ́kọ̀ọ́ tí ọmọkùnrin kan gbà ní ilẹ̀ ọ̀dàn Kánádà àti bí èyí ṣe múra rẹ̀ sílẹ̀ fún ìgbésí ayé míṣọ́nnárì nílẹ̀ Áfíríkà.
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Látinú ìwé Gems From the Coral Islands