ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g05 3/8 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Jí!—2005
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Abiyamọ Kú Ọrọ̀ Ọmọ!
    Jí!—2005
  • Àwọn Abiyamọ Wàhálà Àṣekúdórógbó Tí Wọ́n Ń Ṣe
    Jí!—2002
  • Ìyá Ni Wúrà
    Jí!—2005
  • Òbí Tó Ń Dá Tọ́mọ Túbọ̀ Ń Pọ̀ Sí I
    Jí!—2002
Àwọn Míì
Jí!—2005
g05 3/8 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

March 08, 2005

Iṣẹ́ Àwọn Abiyamọ Gẹ́gẹ́ bí Olùkọ́

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló gbà pé kò yẹ ká kóyán àwọn abiyamọ kéré gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ àwọn ọmọ. Ṣùgbọ́n káàkiri àgbáyé, ìṣòro wo ni wọ́n ń dojú kọ? Báwo ni wọ́n sì ṣe ń jàjàyè lójú irú àwọn ìṣòro bẹ́ẹ̀?

3 Abiyamọ Kú Ọrọ̀ Ọmọ!

5 Àwọn Abiyamọ Tó Ti Jàjàyè

9 Ìyá Ni Wúrà

12 Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . .

Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Máa Fàyè Gba Èrò Òdì?

16 Ojú Ìwòye Bíbélì

Ṣé Ibi Gbogbo Ni Ọlọ́run wà?

18 Tòmátì Èlò Ọbẹ̀ Tí Ìwúlò Ẹ̀ Pọ̀

20 Bí Ìbọ̀rìṣà Àwọn Adúláwọ̀ Ṣe Wọnú Ẹ̀sìn Kátólíìkì

26 Ẹlẹ́wọ̀n Ni Wọ́n, Síbẹ̀ Wọ́n Lómìnira!

28 Ṣé Tẹlifóònù Alágbèéká Dára àbí Kò Dára?

31 ‘Ìwé Ìròyìn Tó Ní Àtìlẹ́yìn Ọlọ́run’

32 Ìpàdé Tó Ṣe Pàtàkì Jù Lọ Lọ́dún Gbogbo Èèyàn La Pè!

“Ká Láwọn Ọ̀dọ́ Mọ̀ Pé Bọ́rọ̀ Ṣe Rí Nìyẹn Ni!” 15

Mo Dúpẹ́ Pé Ìrìn Mi Ò Já Sásán 22

Kà nípa bí ọ̀dọ́mọbìnrin yìí ṣe lọ wàásù Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run fáwọn ẹbí ẹ̀ tí wọ́n wà ní abúlé jíjìnnà réré kan lórílẹ̀-èdè Madagascar.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́