Oro Isaaju
Ìròyìn fi hàn pé àwọn ọ̀dọ́ tó ń ní ìdààmú ọkàn ti wá ń pọ̀ kọjá wẹ́rẹwẹ̀rẹ báyìí.
Kí la lè ṣe nípa ìṣòro yìí?
Ìtẹ̀jáde Jí! yìí jíròrò àwọn ohun tó lè ran àwọn ọ̀dọ́ tó ní ìdààmú ọkàn lọ́wọ́, ó sì tún sọ ohun tí àwọn òbí wọn lè ṣe láti ràn wọ́n lọ́wọ́, kí wọ́n sì tù wọ́n nínú.