Ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀
Ọ̀pọ̀ lára wa ló máa ń sọ pé àwọn kan máa ń ṣe ẹ̀tanú tàbí pé wọ́n lẹ́mìí ìkórìíra. Ṣùgbọ́n, a lè má mọ̀ pé àwa náà máa ń ṣe ẹ̀tanú sáwọn kan.
Jẹ́ ká wo àwọn ìmọ̀ràn tó wúlò táá jẹ́ ká túbọ̀ máa fìfẹ́ hàn sí gbogbo èèyàn.
Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.
Má bínú, fídíò yìí kò jáde.