ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g21 No. 1 ojú ìwé 3
  • Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Tó Ń Mú Káyé Ẹni Dùn

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Tó Ń Mú Káyé Ẹni Dùn
  • Jí!—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
    Jí!—2021
  • Bí A Ṣe Lè Láyọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
  • Ìlú Kan ní Áfíríkà Níbi Tí Àṣà Ìlà Oòrùn àti Ìwọ̀ Oòrùn Ayé Ti Wọnú Ara Wọn
    Jí!—2001
  • Bí A Ṣe Lè Rí Ayọ̀ Tòótọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2001
Àwọn Míì
Jí!—2021
g21 No. 1 ojú ìwé 3
Obìnrin kan jókòó nílé oúnjẹ kan ní Íńdíà, ó ń ronú lórí ohun tó ṣẹ̀ṣẹ̀ kà.

Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Tó Ń Mú Káyé Ẹni Dùn

“Inú mi máa ń bà jẹ́ gan-an nígbà tí mo bá ráwọn ìwà burúkú tó ń ṣẹlẹ̀ láyé, bí ogun, àìsàn, àìríjẹ àìrímu àti bí wọ́n ṣe ń hùwà ìkà sáwọn ọmọdé. Àmọ́ ní báyìí, mo ti wá mọ̀ pé ọ̀la ń bọ̀ wá dáa.”​—RANI.a

Obìnrin tó ń jẹ́ Rani yìí rí ayọ̀ tòótọ́ nígbà tó kẹ́kọ̀ọ́ nípa Ẹlẹ́dàá wa, Ọlọ́run Olódùmarè, tó jẹ́ orísun ọgbọ́n. Bó o ṣe ń ka ìwé yìí, wàá rí bí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ṣe máa jẹ́ . . .

  • kí ìdílé ẹ láyọ̀

  • kó o wà lálàáfíà pẹ̀lú àwọn èèyàn

  • kó o ní ìtẹ́lọ́rùn, kí ọkàn ẹ sì balẹ̀

  • kó o mọ ìdí táwa èèyàn fi ń jìyà, tá a sì ń kú

  • kó dá ẹ lójú pé ọ̀la ń bọ̀ wá dáa

  • kó o mọ Ẹlẹ́dàá wa, kó o sì sún mọ́ ọn

Wàá tún rí i pé gbogbo èèyàn ló lè ní ọgbọ́n Ọlọ́run, tí wọ́n bá ṣáà ti lè wá a.

a A ti yí àwọn orúkọ tá a lò nínú ìwé yìí pa dà.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́