ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • yp2 ojú ìwé 280-281
  • Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Ọlọ́run

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Ọlọ́run
  • Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tí Mo Rò—Ìjọsìn Rẹ
    Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kìíní
  • Ohun Tí Mo Rò—Iléèwé Àtàwọn Ojúgbà Rẹ
    Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì
  • Ohun Tí Mo Rò—Àwọn Òbí Rẹ
    Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì
  • Ohun Tí Mo Rò—Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Ọlọ́run
    Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì
Àwọn Míì
Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè—Àwọn Ìdáhùn Tí Ó Gbéṣẹ́, Apá Kejì
yp2 ojú ìwé 280-281

APÁ 9

Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Ọlọ́run

Èwo ló ṣòro jù fún ẹ lára àwọn gbólóhùn tá a tò sísàlẹ̀ yìí?

□ Kíkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

□ Gbígbàdúrà déédéé sí Jèhófà Ọlọ́run

□ Sísọ ohun tí mo gbà gbọ́ fáwọn ẹlòmíì (àgàgà àwọn ojúgbà mi)

□ Lílóye ìdí tó fi bọ́gbọ́n mu láti máa fàwọn ìlànà Bíbélì ṣèwà hù

Kọ ohun tó o ní lọ́kàn láti ṣe nípa àwọn ohun tó o fàmì sí pé ó ṣòro fún ẹ jù lọ sórí ìlà yìí.

․․․․․

Orí 34 sí 38 nínú ìwé yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti rí bó o ṣe lè mú kí àjọṣe rẹ pẹ̀lú Ọlọ́run fìdí múlẹ̀, bó o ṣe lè máa fi ìlànà Bíbélì ṣèwà hù àti bó o ṣe lè láwọn àfojúsùn tó máa jẹ́ káyé ẹ lójú kó sì nítumọ̀.

[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 280, 281]

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́