APÁ 3 Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tó Ta Yọ Tí Jésù Ṣe ní Gálílì ‘Jésù bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù pé: “Ìjọba Ọ̀run ti sún mọ́lé.”’—Mátíù 4:17