ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 29
  • À Ń Jẹ́ Kí Orúkọ Wa Máa Rò Wá

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • À Ń Jẹ́ Kí Orúkọ Wa Máa Rò Wá
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jíjẹ́ Kí Orúkọ Wa Máa Rò Wá
    Kọrin sí Jèhófà
  • Iṣẹ́ Tá A Fìfẹ́ Ṣe
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Òpò Tá A Fi Ìfẹ́ Ṣe
    Kọrin sí Jèhófà
  • ‘Tọ́ Ọ Wò, Kó O sì Rí I Pé Ẹni Rere Ni Jèhófà’
    “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 29

ORIN 29

À Ń Jẹ́ Kí Orúkọ Wa Máa Rò Wá

Bíi Ti Orí Ìwé

(Àìsáyà 43:10-12)

  1. 1. Jèhófà ológo, Olódùmarè,

    Orísun òótọ́, ọlọ́gbọ́n pípé.

    Òdodo, agbára àtìfẹ́ rẹ pọ̀;

    Ọba Aláṣẹ láyé àtọ̀run.

    Àwa èèyàn rẹ ń láyọ̀ báa ṣe ńsìn ọ́.

    À ń fayọ̀ sọ òótọ́ Ìjọba rẹ.

    (ÈGBÈ)

    Àǹfààní ńlá ni pé a j’Ẹlẹ́rìí rẹ.

    Jọ̀ọ́, jẹ́ kí orúkọ wa máa rò wá.

  2. 2. Ìfẹ́ ń mú ká máa ṣiṣẹ́ ìsìn mímọ́.

    Ó ń mú ká ṣiṣẹ́ pọ̀ lálàáfíà.

    Ẹ̀kọ́ òtítọ́ ń mú káyé wa dára;

    Inú wa ń dùn bá a ṣe ń gbógo rẹ yọ.

    Ẹlẹ́rìí Jèhófà laráyé ń pè wá,

    Èyí ń jẹ́ ká lè fi kún iyì rẹ.

    (ÈGBÈ)

    Àǹfààní ńlá ni pé a j’Ẹlẹ́rìí rẹ.

    Jọ̀ọ́, jẹ́ kí orúkọ wa máa rò wá.

(Tún wo Diu. 32:4; Sm. 43:3; Dán. 2:​20, 21.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́