ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 100
  • Máa Fi Ìfẹ́ Gbà Wọ́n Lálejò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Fi Ìfẹ́ Gbà Wọ́n Lálejò
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Gbà Wọ́n Pẹ̀lú Ẹ̀mí Aájò Àlejò
    Kọrin sí Jèhófà
  • “Ẹ Máa Tẹ̀ Lé Ìlà Ipa Ọ̀nà Aájò Àlejò”
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1996
  • Aájò Àlejò Ṣe Pàtàkì Gan-An
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2018
  • Máa Ṣe Àjọpín “Àwọn Ohun Rere” Nípa Ṣíṣe Aájò Àlejò (Mát. 12:35a)
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 100

ORIN 100

Máa Fi Ìfẹ́ Gbà Wọ́n Lálejò

Bíi Ti Orí Ìwé

(Ìṣe 17:7)

  1. 1. Jèhófà máa ń fìfẹ́ tọ́jú gbogbo wa.

    Ó máa ń fìfẹ́ pèsè fún gbogbo èèyàn.

    Ó ń mú kí oòrùn ràn,

    Ó ńmú kí òjò rọ̀;

    Ó ń fún wa ní oúnjẹ tó dára.

    Ó yẹ káwa náà fara wé Ọlọ́run.

    Ká máa ṣàánú àwọn tó jẹ́ aláìní.

    Ká máa ràn wọ́n lọ́wọ́,

    Kí ara lè tù wọ́n.

    Ká rí i pé a ṣeé látọkàn wá.

  2. 2. Ẹ jẹ́ ká tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Lìdíà

    Tó gba àwọn ẹni mímọ́ lálejò.

    Ẹ̀mí ọ̀làwọ́ wa

    Àtìfẹ́ tá a ń fi hàn

    Yóò fògo fún Bàbá wa ọ̀run.

    Tí àwọn àlejò bá wá sọ́dọ̀ wá,

    Ẹ jẹ́ ká fìfẹ́ gbà wọ́n sínú ‘lé wa.

    Bàbá wa onífẹ̀ẹ́

    Rí gbogbo ‘hun tá à ń ṣe.

    Ó dájú pé yóò pín wa lérè.

(Tún wo Ìṣe 16:14, 15; Róòmù 12:13; 1 Tím. 3:2; Héb. 13:2; 1 Pét. 4:9.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́