Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí:
Òfin wo ló tóbi jù lọ, kí sì nìdí tó fi ṣe pàtàkì? (Mát. 22:37, 38; Máàkù 12:30)
Báwo la ṣe lè yẹra fún ìfẹ́ ayé pátápátá? (1 Jòh. 2:15-17)
Báwo la ṣe lè kọ́ àwọn èèyàn láti “nífẹ̀ẹ́ orúkọ Jèhófà”? (Aísá. 56:6, 7)
Báwo la ṣe lè máa fi ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn hàn sáwọn ará? (1 Jòh. 4:21)
Báwo ni àwọn òbí ṣe lè kọ́ àwọn ọmọ wọn láti nífẹ̀ẹ́ Jèhófà? (Diu. 6:4-9)
Báwo lo ṣe lè fi hàn pé Jèhófà ni Ọ̀rẹ́ tó o fẹ́ràn jù? (1 Jòh. 5:3)
Báwo la ṣe lè máa bá a nìṣó láti nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, báwo la sì ṣe lè tún pa dà nífẹ̀ẹ́ rẹ̀? (Ìṣí. 2:4, 5)