ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • rr ojú ìwé 88-89
  • Àsọtẹ́lẹ̀ Mẹ́ta Nípa Mèsáyà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àsọtẹ́lẹ̀ Mẹ́ta Nípa Mèsáyà
  • Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • 1. “Ẹni Tó Lẹ́tọ̀ọ́ sí I Lọ́nà Òfin” (Ìsíkíẹ́lì 21:25-27)
  • 2. “Ìránṣẹ́ Mi Yóò . . . Máa Bọ́ Wọn, Ó sì Máa Di Olùṣọ́ Àgùntàn Wọn” (Ìsíkíẹ́lì 34:22-24)
  • 3. “Ọba Kan Ni Yóò Máa Ṣàkóso Gbogbo Wọn” Títí Láé (Ìsíkíẹ́lì 37:22, 24-28)
  • “Èmi Yóò Yan Olùṣọ́ Àgùntàn Kan”
    Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Bó O Ṣe Lè Wá Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Nínú Bíbélì Rẹ
    Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
  • Ọdún 1914—Ọdún Pàtàkì Nínú Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì
    Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?
  • Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ìṣàkóso Ìjọba Ọlọ́run Báwo Ló Ṣe Kàn Ọ́?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
Àwọn Míì
Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
rr ojú ìwé 88-89

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 8B

Àsọtẹ́lẹ̀ Mẹ́ta Nípa Mèsáyà

Bíi Ti Orí Ìwé

1. “Ẹni Tó Lẹ́tọ̀ọ́ sí I Lọ́nà Òfin” (Ìsíkíẹ́lì 21:25-27)

ÀKÓKÒ ÀWỌN KÈFÈRÍ (607 Ṣ.S.K.–1914 S.K.)

  1. 607 Ṣ.S.K.​—Wọ́n rọ Sedekáyà lóyè

  2. 1914 S.K.​—Jésù di Ọba, ó sì di Olùṣọ́ Àgùntàn àti Alákòóso, òun ló ní “ẹ̀tọ́ lọ́nà òfin” sí Ìjọba Mèsáyà

Pa dà sí orí 8, ìpínrọ̀ 12 sí 15

2. “Ìránṣẹ́ Mi Yóò . . . Máa Bọ́ Wọn, Ó sì Máa Di Olùṣọ́ Àgùntàn Wọn” (Ìsíkíẹ́lì 34:22-24)

ÀWỌN ỌJỌ́ ÌKẸYÌN (1914 S.K.–LẸ́YÌN AMÁGẸ́DỌ́NÌ)

  1. 1914 S.K.​—Jésù di Ọba, ó sì di Olùṣọ́ Àgùntàn àti Alákòóso, òun ló ní “ẹ̀tọ́ lọ́nà òfin” sí Ìjọba Mèsáyà

  2. 1919 S.K.​—A yan ẹrú olóòótọ́ àti olóye láti máa bójú tó àwọn àgùntàn Ọlọ́run

    A kó àwọn olóòótọ́ ẹni àmì òróró jọ lábẹ́ ìdarí Mèsáyà Ọba; ogunlọ́gọ̀ èèyàn dara pọ̀ mọ́ wọn nígbà tó yá

  3. LẸ́YÌN AMÁGẸ́DỌ́NÌ​—Àwọn ìbùkún tí àkóso Ọba náà mú wá máa wà títí láé

Pa dà sí orí 8, ìpínrọ̀ 18 sí 22

3. “Ọba Kan Ni Yóò Máa Ṣàkóso Gbogbo Wọn” Títí Láé (Ìsíkíẹ́lì 37:22, 24-28)

ÀWỌN ỌJỌ́ ÌKẸYÌN (1914 S.K.–LẸ́YÌN AMÁGẸ́DỌ́NÌ)

  1. 1914 S.K.​—Jésù di Ọba, ó sì di Olùṣọ́ Àgùntàn àti Alákòóso, òun ló ní “ẹ̀tọ́ lọ́nà òfin” sí Ìjọba Mèsáyà

  2. 1919 S.K.​—A yan ẹrú olóòótọ́ àti olóye láti máa bójú tó àwọn àgùntàn Ọlọ́run

    A kó àwọn olóòótọ́ ẹni àmì òróró jọ lábẹ́ ìdarí Mèsáyà Ọba; ogunlọ́gọ̀ èèyàn dara pọ̀ mọ́ wọn nígbà tó yá

  3. LẸ́YÌN AMÁGẸ́DỌ́NÌ​—Àwọn ìbùkún tí àkóso Ọba náà mú wá máa wà títí láé

Pa dà sí orí 8, ìpínrọ̀ 23 sí 26

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́