ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • rr ojú ìwé 140-141
  • Tẹ́ńpìlì Méjì Tó Yàtọ̀ Síra àti Ohun Tó Kọ́ Wa

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Tẹ́ńpìlì Méjì Tó Yàtọ̀ Síra àti Ohun Tó Kọ́ Wa
  • Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìran Tẹ́ńpìlì Tí Ìsíkíẹ́lì Rí:
  • Tẹ́ńpìlì Ńlá Tẹ̀mí:
  • Mọyì Àǹfààní Tó O Ní Láti Jọ́sìn Jèhófà Nínú Tẹ́ńpìlì Tẹ̀mí
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • “Ṣàlàyé Bí Tẹ́ńpìlì Náà Ṣe Rí”
    Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • “Òfin Tẹ́ńpìlì Náà Nìyí”
    Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
  • Ìbùkún Jèhófà Lórí “Ilẹ̀” Wa
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1999
Àwọn Míì
Ìjọsìn Mímọ́ Jèhófà Ti Pa Dà Bọ̀ Sípò!
rr ojú ìwé 140-141
Àwòrán: 1. Àwọn ẹran tí wọ́n fẹ́ fi rúbọ nínú tẹ́ńpìlì tí Ìsíkíẹ́lì rí lójú ìran. 2. Jésù wà lórí òpó igi oró.

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 13A

Tẹ́ńpìlì Méjì Tó Yàtọ̀ Síra àti Ohun Tó Kọ́ Wa

Ìran Tẹ́ńpìlì Tí Ìsíkíẹ́lì Rí:

  • Àwọn Júù tó wà nígbèkùn Bábílónì ni Ìsíkíẹ́lì sọ ọ́ fún

  • Ó ní pẹpẹ kan tí wọ́n ti ń rú onírúurú ẹbọ

  • Ó jẹ́ ká mọ àwọn ìlànà òdodo Jèhófà nípa ìjọsìn mímọ́

  • Ó jẹ́ ká rí bí ìjọsìn mímọ́ ṣe pa dà bọ̀ sípò bẹ̀rẹ̀ láti ọdún 1919

Tẹ́ńpìlì Ńlá Tẹ̀mí:

  • Àwọn Kristẹni tó jẹ́ Hébérù ni Pọ́ọ̀lù ṣàlàyé ẹ̀ fún

  • Ó ní pẹpẹ kan tí wọ́n ti rú ẹbọ kan “lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní ṣe é mọ́ láé” (Héb. 10:10)

  • Ó jẹ́ ká mọ ohun gidi tí àgọ́ ìjọsìn àti tẹ́ńpìlì táwọn ọmọ Ísírẹ́lì lò ṣàpẹẹrẹ, ìyẹn ètò tí Jèhófà ṣe fún ìjọsìn mímọ́ lọ́lá ẹbọ ìràpadà Kristi

  • Ó jẹ́ ká túbọ̀ rí iṣẹ́ tí Kristi tó jẹ́ Àlùfáà Àgbà Tó Tóbi Jù ṣe látọdún 29 sí 33 Sànmánì Kristẹni.

Pa dà sí orí 13, ìpínrọ̀ 7 sí 14

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́