ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • syr19 ojú ìwé 2
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2019

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2019
  • 2019 Ìròyìn Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2020
    2020 Ìròyìn Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2018
    2018 Ìròyìn Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2021
    2021 Ìròyìn Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé
  • Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2017
    2017 Ìròyìn Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé
Àwọn Míì
2019 Ìròyìn Ọdún Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé
syr19 ojú ìwé 2

Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2019

  • Iye Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà: 87

  • Iye Orílẹ̀-Èdè Tó Ròyìn: 240

  • Àròpọ̀ Iye Ìjọ: 119,712

  • Àwọn Tó Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi Kárí Ayé: 20,919,041

  • Àwọn Tó Jẹ Ohun Ìṣàpẹẹrẹ Kárí Ayé: 20,526

  • Góńgó Akédea: 8,683,117

  • Ìpíndọ́gba Akéde Tó Ń Wàásù Lóṣooṣù: 8,471,008

  • Iye Tá A Fi Pọ̀ Ju Ti Ọdún 2018: 103,208

  • Àròpọ̀ Iye Àwọn Tó Ṣèrìbọmib: 303,866

  • Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Déédééc Lóṣooṣù: 1,277,738

  • Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣooṣù: 464,980

  • Àròpọ̀ Wákàtí Tá A Lò Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù: 2,088,560,437

  • Ìpíndọ́gba Àwọn Tá À Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélìd Lóṣooṣù: 9,618,182

Ní ọdún iṣẹ́ ìsìn 2019,e àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ná ohun tó lé ní ọgọ́rùn-ún méjì ó lé mẹ́rìnlélógún (224) mílíọ̀nù dọ́là láti bójú tó àwọn aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe, àwọn míṣọ́nnárì àtàwọn alábòójútó àyíká lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wọn. Kárí ayé, iye àwọn tó ń ṣiṣẹ́ láwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jẹ́ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún, ọgọ́rùn-ún mẹ́jọ ó lé méjìdínlọ́gọ́ta (20,858). Gbogbo wọn wà lára Àwọn Tó Ń Ṣe Àkànṣe Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún Lára Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.

a Akéde ni àwọn tó ń kéde tàbí tó ń wàásù ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run déédéé. (Mátíù 24:14) Tó o bá fẹ́ àlàyé síwájú sí i nípa bá a ṣe mọ iye wọn, wo àpilẹ̀kọ náà “Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Mélòó Ló Wà Kárí Ayé?” lórí ìkànnì jw.org/yo.

b Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa àwọn ohun tẹ́nì kan máa ṣe kó tó ṣe ìrìbọmi láti di ọ̀kan lára àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, wo àpilẹ̀kọ náà “Báwo Ni Mo Ṣe Lè Di Ẹlẹ́rìí Jèhófà?” lórí ìkànnì jw.org/yo.

c Aṣáájú-ọ̀nà ni Ẹlẹ́rìí kan tó ti ṣe ìrìbọmi tó sì níwà tó dáa. Ó pinnu láti máa lo iye wákàtí kan pàtó lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù ìhìn rere lóṣooṣù.

d Tó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i, wo àpilẹ̀kọ tá a pè ní “Kí Là Ń Pè Ní Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?” lórí ìkànnì jw.org/⁠yo.

e Ọdún iṣẹ́ ìsìn 2019 bẹ̀rẹ̀ láti September 1, 2018, ó sì parí ní August 31, 2019.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́