ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm22 ojú ìwé 8
  • Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá sí Àpéjọ Yìí Mọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá sí Àpéjọ Yìí Mọ̀
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá sí Àpéjọ Yìí Mọ̀
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2021
  • Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá sí Àpéjọ Yìí Mọ̀
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2020
  • Ohun tá a fẹ́ kí àwọn tó wá sí àpéjọ yìí mọ̀
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2023
  • Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá Sí Àpéjọ Yìí Mọ̀
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2022
CO-pgm22 ojú ìwé 8

Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá sí Àpéjọ Yìí Mọ̀

Ìrìbọmi Àwọn alàgbà ìjọ yín ti ṣètò tó bá àdúgbò yín mu kí àwọn tó bá kúnjú ìwọ̀n lè ṣèrìbọmi lẹ́yìn ìpàdé àárọ̀ Saturday.

Ọrẹ A túmọ̀ gbogbo àpéjọ yìí sí èdè tó lé ní ọgọ́rùn-ún márùn-ún (500). Ọrẹ tẹ́ ẹ̀ ń ṣe ń ṣètìlẹyìn fún iṣẹ́ tá à ń ṣe kárí ayé. Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ, jọ̀wọ́ lọ sórí Ìkànnì donate.jw.org. A mọrírì gbogbo ọrẹ tẹ́ ẹ bá ṣe. Ìgbìmọ̀ Olùdarí sì fẹ́ fi àkókò yìí dúpẹ́ lọ́wọ́ yín fún bẹ́ ẹ ṣe ń fi owó yín ti Ìjọba Ọlọ́run lẹ́yìn.

Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere Ìjọba Ọlọ́run

Tọkọtaya kan ń fi ìwé “Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!” kọ́ ọkùnrin kan lẹ́kọ̀ọ́

Kí àwọn aṣáájú-ọ̀nà tí ọjọ́ orí wọn wà láàárín ọdún mẹ́tàlélógún (23) sí márùndínláàádọ́rin (65), tí wọ́n fẹ́ túbọ̀ tẹ̀ síwájú lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn wọn kàn sí akọ̀wé ìjọ wọn, kí wọ́n sì lọ sórí ìkànnì jw.org láti kọ ọ̀rọ̀ sí fọ́ọ̀mù tó wà fún àwọn tó fẹ́ lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere Ìjọba Ọlọ́run.

Tí Ìgbìmọ̀ Olùdarí Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣètò

© 2022 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́