Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2024
Iye Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà: 84
Iye Orílẹ̀-Èdè Tó Ròyìn: 240
Iye Ìjọ: 118,767
Àwọn Tó Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi Kárí Ayé: 21,119,442
Àwọn Tó Jẹ Ohun Ìṣàpẹẹrẹ Kárí Ayé: 23,212
Iye Akédea: 9,043,460
Ìpíndọ́gba Akéde Tó Ń Wàásù Lóṣooṣù: 8,828,124
Iye Tá A Fi Pọ̀ Ju Ti Ọdún 2023: 203,082
Iye Àwọn Tó Ṣèrìbọmib: 296,267
Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Déédééc Lóṣooṣù: 1,679,026
Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣooṣù: 867,502
Ìpíndọ́gba Àwọn Tá À Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélìd Lóṣooṣù: 7,480,146
Ọdún iṣẹ́ ìsìn 2024 bẹ̀rẹ̀ láti September 1, 2023 sí August 31, 2024.
a Akéde ni ẹni tó ń kéde tàbí tó ń wàásù ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run déédéé. (Mátíù 24:14) Tó o bá fẹ́ àlàyé nípa bá a ṣe mọ iye àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, wo àpilẹ̀kọ náà “Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Mélòó Ló Wà Kárí Ayé?” lórí jw.org.
b Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa àwọn nǹkan tẹ́nì kan máa ṣe kó tó lè ṣèrìbọmi láti di ọ̀kan lára àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, wo àpilẹ̀kọ náà “Báwo Ni Mo Ṣe Lè Di Ẹlẹ́rìí Jèhófà?” lórí jw.org.
c Aṣáájú-ọ̀nà ni Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan tó ti ṣèrìbọmi, tó níwà tó dáa, tó sì pinnu láti máa lo iye wákàtí kan pàtó lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù ìhìn rere lóṣooṣù.
d Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i, wo àpilẹ̀kọ tá a pè ní “Kí Ni Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn?” lórí jw.org.