Oro Isaaju
KÍ LÈRÒ RẸ?
Tí ẹnì kan bá béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé báwo ni ọ̀run ṣe rí, kí lo máa sọ?
A lè kẹ́kọ̀ọ́ lọ́dọ̀ Jésù torí ó sọ pé: “Èmi wá láti àwọn ilẹ̀ àkóso òkè.”—Jòhánù 8:23.
Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ yìí ṣàlàyé ohun tí Jésù àti Bàbá rẹ̀ sọ nípa ọ̀run.