ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • wp18 No. 1 ojú ìwé 16
  • Kí Lèrò Rẹ?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Lèrò Rẹ?
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2018
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣé Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run?
  • OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ
  • Ọlọ́run Ń Pè Ọ́ Pé Kí O Wá Di Ọ̀rẹ́ Òun
    Ìwọ Lè Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run!
  • Bó O Ṣe Lè Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ọ̀rẹ́?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Báwo Lèèyàn Ṣe Lè Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Gidi?
    Jí!—2014
Àwọn Míì
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde)—2018
wp18 No. 1 ojú ìwé 16
Ọkọ àtìyàwó kan ń ka Bíbélì nígbà tí wọ́n ṣeré jáde

Kí Lèrò Rẹ?

Ṣé Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run?

ÀWỌN KAN GBÀ PÉ . . .

àwọn ò lè di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run torí wọ́n rò pé aláìmọ́ àti ẹlẹ́ṣẹ̀ ni àwọn. Àwọn míì sọ pé Ọlọ́run ò rí ti àwa èèyàn rò. Kí lèrò rẹ?

OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ

“Ìbárẹ́ tímọ́tímọ́ [Ọlọ́run] wà pẹ̀lú àwọn adúróṣánṣán.” (Òwe 3:32) A máa di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run tí a bá ń ṣègbọràn sí i.

KÍ LÀWỌN NǸKAN MÍÌ TÍ BÍBÉLÌ SỌ?

  • Ọlọ́run fẹ́ di Ọ̀rẹ́ wa.​—Jákọ́bù 4:8.

  • Torí pé Ọlọ́run jẹ́ Ọ̀rẹ́ wa, ó múra tán láti ràn wá lọ́wọ́ kó sì dárí jì wá.​—Sáàmù 86:5.

  • Àwọn ọ̀rẹ́ Ọlọ́run máa ń nífẹ̀ẹ́ ohun tí Ọlọ́run fẹ́, wọ́n sì máa ń kórìíra ohun tí Ọlọ́run kò fẹ́.​—Róòmù 12:9.

Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa bó o ṣe lè gbé ìgbé ayé tó máa múnú Ọlọ́run dùn, ka orí 12 nínú ìwé yìí, Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é. Ó tún wà lórí ìkànnì wa www.jw.org/yo

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́