ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 December ojú ìwé 4
  • Dúró sí “Àfonífojì Àwọn Òkè Ńlá”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Dúró sí “Àfonífojì Àwọn Òkè Ńlá”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Dúró Sí Ibi Ààbò Jèhófà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 December ojú ìwé 4
Àwọn èèyàn ń rìn ní àárín “àfonífojì àwọn òkè ńlá”

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SEKARÁYÀ 9-14

Dúró sí “Àfonífojì Àwọn Òkè Ńlá”

14:3-5

Jèhófà ṣe “afonífojì ńlá” kan lọ́dún 1914 nígbà tó gbé Ìjọba Mèsáyà kalẹ̀, Ìjọba yìí tó jẹ́ “òkè ńlá” wà lábẹ́ àkóso rẹ̀. Láti ọdún 1919, “àfonífojì àwọn òkè ńlá” náà ti di ibi ààbò fún àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run

Báwo ni àwọn èèyàn ṣe ń “sá lọ sí àfonífojì” ààbò?

14:​12, 15

Àwọn tí kò bá dúró sí àfonífojì náà máa pa run nígbà Amágẹ́dọ́nì

Báwo ni mo ṣe lè dúró sí àfonífojì ààbò?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́