ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 August ojú ìwé 4
  • Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àpèjúwe Mínà Mẹ́wàá

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àpèjúwe Mínà Mẹ́wàá
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àpèjúwe Nípa Àwọn Tálẹ́ńtì Náà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2015
  • Àkàwé Nipa Mina
    Ọkunrin Titobilọla Julọ Ti O Tii Gbé Ayé Rí
  • Àpèjúwe Mínà Mẹ́wàá
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
  • Ẹ̀kọ́ Tí Àpèjúwe Tálẹ́ńtì Kọ́ Wa
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 August ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÚÙKÙ 19-20

Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Àpèjúwe Mínà Mẹ́wàá

19:12-24

Ọ̀gá, àwọn ẹrú àti àpò owó

Kí ni ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn apá tó wà nínú àpèjúwe náà dúró fún?

  1. Ọ̀gá náà ṣàpẹẹrẹ Jésù

  2. Àwọn ẹrú yẹn ṣàpẹẹrẹ àwọn ẹni àmì òróró ọmọlẹ́yìn Jésù

  3. Owó tí ọ̀gá náà gbé fún àwọn ẹrú rẹ̀ ṣàpẹẹrẹ iṣẹ́ sísọ àwọn èèyàn di ọmọlẹ́yìn, tó jẹ́ iṣẹ́ pàtàkì

Àpèjúwe yìí jẹ́ ìkìlọ̀ tó jẹ́ ká mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ tí àwọn ẹni àmì òróró ọmọlẹ́yìn Kristi bá lọ ní irú ìwà tí ẹrú burúkú yẹn ní. Jésù retí pé káwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ lo ohun ìní wọn lẹ́nu iṣẹ́ sísọ àwọn èèyàn di ọmọ ẹ̀yìn.

Báwo ni mo ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ àwọn Kristẹni ẹni àmì òróró lẹ́nu iṣẹ́ sísọ àwọn èèyàn di ọmọ ẹ̀yìn?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́