ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb18 December ojú ìwé 4
  • Wọ́n Fìmọ̀ Ṣọ̀kan Láti Ṣe Ìpinnu Tó Dá Lórí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Wọ́n Fìmọ̀ Ṣọ̀kan Láti Ṣe Ìpinnu Tó Dá Lórí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ọ̀nà Wo Ni Ìgbìmọ̀ Olùdarí Gbà Ń Ṣiṣẹ́ Lóde Òní?
    Àwọn Wo Ló Ń Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà Lóde Òní?
  • Ta Ló Ń Darí Àwa Èèyàn Ọlọ́run Lónìí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • “A Ti Fìmọ̀ Ṣọ̀kan”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
  • Ta Ni “Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye”?
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
mwb18 December ojú ìwé 4
Ìjọ kan ní ọgọ́rùn-⁠ún ọdún kìíní ń tẹ́tí sí ìpinnu tí ìgbìmọ̀ olùdarí ṣe

Ìjọ kan ń tẹ́tí sí ìpinnu tí ìgbìmọ̀ olùdarí ṣe

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 15-16

Wọ́n Fìmọ̀ Ṣọ̀kan Láti Ṣe Ìpinnu Tó Dá Lórí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run

Ẹ̀kọ́ wo la rí kọ́ nínú bí wọ́n ṣe yanjú ìṣòro náà?

15:1, 2​—Jẹ́ ẹlẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀ àti onísùúrù. Pọ́ọ̀lù àti Bánábà ò fi ọgbọ́n ara wọn yanjú ọ̀rọ̀ náà, ṣe ni wọ́n béèrè ìtọ́sọ́nà lọ́dọ̀ ètò Ọlọ́run.

15:28, 29​—Fọkàn tán ètò Ọlọ́run. Ó dá ìjọ lójú pé Jèhófà máa lo ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀ àti Jésù láti yanjú ọ̀rọ̀ náà.

16:4, 5​—Jẹ́ onígbọràn. Àwọn ìjọ ń pọ̀ sí i bí wọ́n ṣe ń tẹ̀ lé ìtọ́ni tí ìgbìmọ̀ olùdarí ń fún wọn.

Ìtọ́ni wo ni ètò Ọlọ́run fún wa láìpẹ́ yìí?

Àǹfààní wo ni mo rí nígbà tí mo tẹ̀ lé e?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́