ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 April ojú ìwé 1
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ●○○NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
  • ○●○ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
  • ○○●ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
  • ÌKÉSÍNI SÍ ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (March 23–April 19):
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 April ojú ìwé 1
Tọkọtaya kan ń kí ẹni tuntun kan káàbọ̀ sí Ìrántí Ikú Kristi

Wọ́n ń kí ẹni tuntun kan káàbọ̀ sí Ìrántí Ikú Kristi

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Ta ni Jésù?

Bíbélì: Mt 16:16

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tí Jésù fi kú?

○●○ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí nìdí tí Jésù fi kú?

Bíbélì: Mt 20:28

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọyì bí Jésù ṣe kú fún wa?

○○●ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọyì bí Jésù ṣe kú fún wa?

Bíbélì: Jo 17:3

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń ṣe láwọn ìpàdé wa?

ÌKÉSÍNI SÍ ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (March 23–April 19):

A fẹ́ pè yín sí ìpàdé pàtàkì kan. Ìwé ìkésíni tiyín rèé. Ní Friday, April 19, ọ̀pọ̀ èèyàn kárí ayé máa pé jọ láti ṣe ìrántí ikú Jésù Kristi. Ẹ máa rí àkókò àti ibi tá a ti máa ṣe ìpàdé náà nínú ìwé yìí. A tún fẹ́ kẹ́ ẹ wá gbọ́ àsọyé kan ní ọ̀sẹ̀ tó ṣáájú ìgbà yẹn, àkòrí rẹ̀ ni “Sapá Kó O Lè Ní Ìyè Tòótọ́!”

Tí Ẹni Náà Bá Nífẹ̀ẹ́ Sí Ọ̀rọ̀ Rẹ, Fi Ìbéèrè Yìí Sílẹ̀: Kí nìdí tí Jésù fi kú?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́