ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 September ojú ìwé 8
  • Jẹ́ Onígboyà Bíi Ti Ásà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jẹ́ Onígboyà Bíi Ti Ásà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Ẹ̀san Wà fún Ìgbòkègbodò Yín”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n ní Àkókò Àlàáfíà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2020
  • Fi Ọkàn Pípé Pérépéré Sin Jèhófà!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • Àwọn Ọ̀nà Tí Jèhófà Gbà Ń Sún Mọ́ Wa
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2014
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 September ojú ìwé 8

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jẹ́ Onígboyà Bíi Ti Ásà

Ásà fìtara gbèjà ìjọsìn mímọ́ (1Ọb 15:11, 12; w12 8/15 8 ¶4)

Ásà nígboyà, ó sì ka ìjọsìn Jèhófà sí pàtàkì ju àjọṣe tó wà láàárín òun àtàwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀ (1Ọb 15:13; w17.03 19 ¶7)

Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Ásà ṣàṣìṣe, Jèhófà kà á sí olóòótọ́ torí ẹ̀mí rere tó ní (1Ọb 15:14, 23; it-1 184-185)

Ọmọkùnrin kan kó ẹrù ẹ̀, ó sì ń filé sílẹ̀. Bàbá rẹ̀ gbá ìyá rẹ̀ tó ń sunkún àti ọmọbìnrin wọn mọ́ra.

BI ARA RE PÉ: ‘Ṣé mo ní ìtara fún ìjọsìn mímọ́? Ṣé mi kì í bá àwọn tó bá fi Jèhófà sílẹ̀ kẹ́gbẹ́, kódà tí wọ́n bá jẹ́ mọ̀lẹ́bí mi?’—2Jo 9, 10.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́