ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 September ojú ìwé 16
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àkànṣe Ìwàásù Láti Bẹ̀rẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì (September 1-30)
  • Nígbà Àkọ́kọ́
  • Ìpadàbẹ̀wò
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 September ojú ìwé 16
Àwòrán: 1. Tọkọtaya kan fún ọkùnrin kan ní ìwé “Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!” nílé rẹ̀. 2. Arábìnrin kan ń fi ìwé náà kọ́ obìnrin kan lẹ́kọ̀ọ́. 3. Arákùnrin kan ń fi ìwé “Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!” kọ́ ọkùnrin kan tó ń tajà lẹ́kọ̀ọ́.

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Àkànṣe Ìwàásù Láti Bẹ̀rẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì (September 1-30)

Ìbéèrè: Ǹjẹ́ ẹ ronú pé àwa èèyàn lè wà láàyè títí láé?

Bíbélì: Sm 37:29

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ǹjẹ́ a lè gba ohun tí Bíbélì sọ gbọ́?

Nígbà Àkọ́kọ́

Ìbéèrè: Ibo la ti lè rí ìmọ̀ràn tó dáa nípa bá a ṣe lè máa gbé ìgbé ayé wa?

Bíbélì: 2Ti 3:16, 17

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tó o fi lè gba ohun tí Bíbélì sọ gbọ́?

Ìpadàbẹ̀wò

Ìbéèrè: Kí nìdí tó o fi lè gba ohun tí Bíbélì sọ gbọ́?

Bíbélì: Job 26:7

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Àwọn ìbéèrè wo ni Bíbélì dáhùn?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́