ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 July ojú ìwé 4
  • Ẹ́sírà Fi Ìwà Rẹ̀ Gbé Orúkọ Jèhófà Ga

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ́sírà Fi Ìwà Rẹ̀ Gbé Orúkọ Jèhófà Ga
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ́sírà Kọ́ Àwọn Èèyàn ní Òfin Ọlọ́run
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • Ǹjẹ́ Bó O Ṣe Ń Kọ́ni Múná Dóko?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2002
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ẹ́sírà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
  • Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Ẹ Lójú Pé Jèhófà Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Nígbà Ìṣòro
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 July ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ẹ́sírà Fi Ìwà Rẹ̀ Gbé Orúkọ Jèhófà Ga

Ẹ́sírà jẹ́ kí ohun tó kọ́ nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wọ̀ ọ́ lọ́kàn, ó sì hàn nínú ìwà rẹ̀ (Ẹsr 7:10; w00 10/1 14 ¶8)

Àwọn èèyàn rí i pé Ọlọ́run fún Ẹ́sírà lọ́gbọ́n (Ẹsr 7:25; si 75 ¶5)

Ẹ́sírà rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ níwájú Ọlọ́run, ìyẹn mú kó dá a lójú pé Jèhófà máa tọ́ òun sọ́nà, á sì dáàbò bo òun (Ẹsr 8:21-23; it-1 1158 ¶4)

Ọ̀gá mẹkáníìkì kan ń gbóríyìn fún arákùnrin tó ń bá a ṣiṣẹ́.

Àwọn ohun tí Ẹ́sírà ṣe fi hàn pé ó ní ọgbọ́n Ọlọ́run, ìyẹn sì mú kí ọba gbé àwọn iṣẹ́ pàtàkì fún un. Bíi ti Ẹ́sírà, àwa náà lè fi ìwà wa gbé orúkọ Jèhófà ga.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé ìwà mi máa ń mú káwọn tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà bọ̀wọ̀ fún mi?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́