MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
Nígbà Àkọ́kọ́
Ìbéèrè: Tá a bá wà nínú ìṣòro, kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé Ọlọ́run kọ́ ló ń fìyà jẹ wá?
Bíbélì: Jem 1:13
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tá a fi ń jìyà?
WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:
Ìpadàbẹ̀wò
Ìbéèrè: Kí nìdí tá a fi ń jìyà?
Bíbélì: 1Jo 5:19
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló jẹ́ ká mọ̀ pé inú Ọlọ́run ò dùn sí ìyà tó ń jẹ wá?
WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́: