ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • yb15 ojú ìwé 10-ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 1
  • Ise N Yara Te Siwaju Niluu Warwick

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ise N Yara Te Siwaju Niluu Warwick
  • Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2015
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Báwo Ni Iṣẹ́ Ṣe Ń Lọ Sí Ní Warwick?
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2016
  • Ètò Ọlọ́run Ń Tẹ̀ Síwájú
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2014
  • Àwọn Ohun Pàtàkì Tó Ṣẹlẹ̀ Lọ́dún Tó Kọjá
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2017
  • Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—ní New York
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2015
Àwọn Míì
Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2015
yb15 ojú ìwé 10-ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 1
Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 10, 11

ÀWỌN OHUN PÀTÀKÌ TÓ ṢẸLẸ̀ LỌ́DÚN TÓ KỌJÁ

Iṣẹ́ Ń Yára Tẹ̀ Síwájú Nílùú Warwick

Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 12

BÍ ARA àwọn èèyàn ṣe ń yá gágá, bẹ́ẹ̀ ni iṣẹ́ ń lọ ní pẹrẹu níbi tá a fẹ́ fi ṣe oríléeṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ìlú Warwick, ìpínlẹ̀ New York, ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ọgọ́rọ̀ọ̀rún àwọn ará wa lọ́kùnrin àti lóbìnrin ló ti yááfì ọ̀pọ̀ nǹkan kí wọ́n lè wá kópa nínú iṣẹ́ ìkọ́lé náà. Síbẹ̀, ọ̀pọ̀ wọn ló ń sọ pé, “A ò ní jẹ́ kí ohunkóhun gba àǹfààní tá a ní láti ṣiṣẹ́ níbí mọ́ wa lọ́wọ́.” Ẹ jẹ́ ká jọ wo ohun tó ń lọ nílùú Warwick.

Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 13

Báwo ló ṣe rí lára àwọn tó ń ṣiṣẹ́ ní Warwick?

Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 13

“Iṣẹ́ tó ń lọ ní Warwick yìí kì í ṣe ọ̀rọ̀ ilé kíkọ́ lásán. Jèhófà ń mú kí onírúurú ẹgbẹ́ tó ń kọ́lé wà níṣọ̀kan, ó sì ń jẹ́ ká túbọ̀ ronú lórí bá a ṣe ń yàwòrán àti bá a ṣe ń ṣètò àwọn iṣẹ́ ìkọ́lé tó ṣe pàtàkì.”—Enrique Ford.

Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 13

“Sáàmù 127:1 sọ pé: ‘Bí kò ṣe pé Jèhófà tìkára rẹ̀ bá kọ́ ilé náà, lásán ni àwọn tí ń kọ́ ọ ti ṣiṣẹ́ kárakára lórí rẹ̀.’ Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ká rí i kedere pé ìbùkún Jèhófà ló lè mú ká ṣe àṣeyọrí gidi nídìí iṣẹ́ yìí.”—Troy Snyder.

Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 13

“Kò tíì sí ohun tó fún ìgbàgbọ́ mí lókun bíi ti iṣẹ́ yìí.”—Richard Devine.

Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 14, 15
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́