ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ijwfq àpilẹ̀kọ 4
  • Ṣé ẹ rò pé ẹ̀yin nìkan ló máa rí ìgbàlà?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé ẹ rò pé ẹ̀yin nìkan ló máa rí ìgbàlà?
  • Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣáwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Gbọ́ Pé Àwọn Nìkan Làwọn Máa Nígbàlà?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2008
  • Kí Ni Ìgbàlà?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Ìgbàlà Ohun Tí Ó Túmọ̀ Sí Gan-An
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1997
  • Ṣé Bíbélì Kọ́ni Pé ‘Téèyàn Bá Ti Rígbàlà Lẹ́ẹ̀kan, Ó Ti Rígbàlà Títí Ayé Nìyẹn’?
    Ohun Tí Bíbélì Sọ
Àwọn Míì
Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
ijwfq àpilẹ̀kọ 4
Àwọn èèyàn láti ibi ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ń gbàdúrà

Ṣé ẹ rò pé ẹ̀yin nìkan ló máa rí ìgbàlà?

Rárá o. Ọ̀kẹ́ àìmọye àwọn tó gbé láyé láwọn ìgbà pípẹ́ sẹ́yìn, tí wọn kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa rí ìgbàlà. Bíbélì ṣàlàyé pé nínú ayé tuntun tí Ọlọ́run ṣèlérí, “àjíǹde àwọn olódodo àti àwọn aláìṣòdodo yóò wà.” (Ìṣe 24:15) Yàtọ̀ síyẹn, ó ṣeé ṣe kí ọ̀pọ̀ àwọn èèyàn tó wà láàyè lónìí bẹ̀rẹ̀ sí í sin Ọlọ́run, kí àwọn pẹ̀lú sì rí ìgbàlà. Èyí ó wù kó jẹ́, iṣẹ́ wa kọ́ ni láti pinnu àwọn tó máa rí ìgbàlà àti àwọn tí kò ní rí i. Iṣẹ́ Jésù ni.—Jòhánù 5:22, 27.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́