ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ijwfq àpilẹ̀kọ 11
  • Ṣé Ẹ̀ya Ìsìn Amẹ́ríkà ni Ẹ̀sìn Yín?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Ẹ̀ya Ìsìn Amẹ́ríkà ni Ẹ̀sìn Yín?
  • Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Awọn Kristian ati Ẹgbẹ́ Awujọ Eniyan Lonii
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
  • Àwọn Ìbéèrè Tí Àwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè
    Jí!—2010
  • Ẹgbẹ́ Awo Ha Ni Àwọn Ẹlẹ́rìí Jehofa Bí?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1994
  • Ibo La Ti Lè Rí—Aṣáájú Rere?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2002
Àwọn Míì
Àwọn Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Sábà Máa Ń Béèrè Nípa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
ijwfq àpilẹ̀kọ 11
Àwọn èèyàn aláyọ̀ láti oríṣiríṣi orílẹ̀-èdè

Ṣé Ẹ̀ya Ìsìn Amẹ́ríkà Ni Ẹ̀sìn Yín?

Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ni orílé-iṣẹ́ wa àgbáyé wà. Àmọ́, ẹ̀sìn wa kì í ṣe ẹ̀ya ìsìn Amẹ́ríkà, àwọn ohun tó mú ka sọ bẹ́ẹ̀ rèé:

  • Àwọn kan ka ẹ̀ya ìsìn sí àwùjọ kan tó ya kúrò lára ẹ̀sìn tó ti wà tẹ́lẹ̀. Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà kò ya kúrò lára àwọn ẹ̀sìn mìíràn. Kàkà bẹ́ẹ̀, ńṣe la pa dà sí bí wọ́n ṣe ń ṣe ẹ̀sìn Kristẹni ní ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní.

  • Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń wàásù déédéé ní ilẹ̀ àti orílẹ̀-èdè tó ju ọgbọ̀n lé ní igba [230] lọ. Ibi yòówù tí a ń gbé, a jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà Ọlọ́run àti Jésù Kristi, kì í ṣe sí Ìjọba ilẹ̀ Amẹ́ríkà tàbí ìjọba èèyàn èyíkéyìí.—Jòhánù 15:19; 17:15, 16.

  • Gbogbo ẹ̀kọ́ wa ló wá látinú Bíbélì, kì í ṣe látinú ìwé àwọn olórí ìsìn kan nílẹ̀ Amẹ́ríkà.​—1 Tẹsalóníkà 2:13.

  • Jésù Kristi ni à ń tẹ̀ lé, kì í ṣe èèyàn èyíkéyìí tó jẹ́ olórí.—Mátíù 23:8-10.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́