ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ijwbq àpilẹ̀kọ 15
  • Ṣé Jésù Ni Ọlọ́run Olódùmarè?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Jésù Ni Ọlọ́run Olódùmarè?
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tí Bíbélì Sọ
  • Igba Gbogbo Ha Ni Ọlọrun Ga Lọ́lá Jù Jesu Bí?
    Iwọ Ha Nilati Gbàgbọ́ Ninu Mẹtalọkan Bí?
  • Ṣé Jésù Ni Ọlọ́run Olódùmarè?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Ki Ni Iwe Mímọ́ Sọ Nipa “Ipo Jíjẹ́ Ọlọrun Kristi”?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1992
  • Òtítọ́ Nípa Baba, Ọmọ, àti Ẹ̀mí Mímọ́
    Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?
Àwọn Míì
Ohun Tí Bíbélì Sọ
ijwbq àpilẹ̀kọ 15
Jésù

Ṣé Jésù Ni Ọlọ́run Olódùmarè?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Àwọn tó ń tako Jésù fẹ̀sùn kàn án pé ó sọ pé òun bá Ọlọ́run dọ́gba. (Jòhánù 5:18; 10:30-33) Àmọ́, Jésù kò fìgbà kan sọ pé òun bá Ọlọ́run Olódùmarè dọ́gba. Ó sọ pé: “Baba tóbi jù mí lọ.”—Jòhánù 14:28.

Àwọn tó kọ́kọ́ di ọmọ ẹ̀yìn Jésù kò gbà pé Jésù bá Ọlọ́run Olódùmarè dọ́gba. Bí àpẹẹrẹ, àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ pé lẹ́yìn tí Ọlọ́run jí Jésù dìde, “Ó gbé [Jésù] sí ipò gíga.” Ó dájú pé Pọ́ọ̀lù kò gbà gbọ́ pé Jésù ni Ọlọ́run Olódùmarè. Bó bá jẹ́ pé Jésù ni Ọlọ́rùn Olódùmarè ni, Bíbélì kò ní sọ pé Ọlọ́rùn tún gbé e sí ipò gíga.—Fílípì 2:9.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́