KẸ́KỌ̀Ọ́ LÁRA ÀWỌN Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ
Jóṣúà àti Kélẹ́bù
Lo eré yìí láti kẹ́kọ̀ọ́ lára Jóṣúà àti Kélẹ́bù tó jẹ́ ọ̀rẹ́ Jèhófà.
Ẹ̀yin òbí, ẹ ka Nọ́ńbà 13:30–14:10 pẹ̀lú àwọn ọmọ yín, kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀.
Wa eré yìí jáde, kó o sì tẹ̀ ẹ́ sórí ìwé.
Tẹ̀ lé àbá tó wà lójú ìwé àkọ́kọ́ láti gé àwọn àwòrán tó wà níbẹ̀, kó o sì tò wọ́n sójú ìwé kejì. Bẹ́ ẹ ṣe ń ṣiṣẹ́ lórí àwòrán yìí, ẹ dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà nínú fídíò náà. Tó o bá ní àwọn àwòrán míì tó o ti gé nínú àwọn eré tó ti jáde tẹ́lẹ̀, o lè tò ó pọ̀ kó o fi ṣe ìwé.