Àfikún Àlàyé ^ 2. Ọ̀jọ̀gbọ́n Yan-Der Hsuuw kì í fi ọlẹ̀ èèyàn ṣe ìwádìí torí pé gẹ́gẹ́ bíi Kristẹni, ẹ̀rí ọkàn rẹ̀ kò gbé e.