Àfikún Àlàyé
^ [1] (ìpínrọ̀ 9) Tó o bá fẹ́ kà nípa bí àwọn ará wa ṣe fìfẹ́ hàn síra wọn nígbà àjálù, wo Ilé Ìṣọ́ July 15, 2002, ojú ìwé 8 sí 9 àti ìwé Jehovah’s Witnesses—Proclaimers of God’s Kingdom, orí 19. O tún lè wo fídíò náà, “Gbogbo Ẹgbẹ́ Àwọn Ará Wa.”