Àfikún Àlàyé ^ [2] (ìpínrọ̀ 15) Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Ìṣe 2:33 fi hàn pé Jésù náà máa ń mọ̀ sí i tẹ́nì kan bá di ẹni àmì òróró, Jèhófà ló yan onítọ̀hún.