Àfikún Àlàyé
^ [1] (ìpínrọ̀ 7) Lára ohun tí Jésù sọ fún wọn ni pé: (1) Kí wọ́n máa wàásù nípa Ìjọba Ọlọ́run. (2) Kí wọ́n jẹ́ kí ohun tí wọ́n ní tẹ́ wọn lọ́rùn. (3) Kí wọ́n má ṣe bá àwọn tí wọ́n ń wàásù fún jiyàn. (4) Kí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run táwọn kan bá ta kò wọ́n. (5) Wọn ò gbọ́dọ̀ bẹ̀rù.