Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé Ìyẹn, gbogbo ohun tí wọ́n yà sí mímọ́ fún Ọlọ́run tí kò ṣeé gbà pa dà, tí kò sì ṣeé rà pa dà lọ́wọ́ Ọlọ́run.