Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé Dọ́káàsì jẹ́ orúkọ Gíríìkì, Tàbítà jẹ́ orúkọ Árámáíkì, orúkọ méjèèjì túmọ̀ sí “Egbin.”