Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé Tàbí “ìbẹ̀rẹ̀ àti òpin.” Ááfà ni lẹ́tà àkọ́kọ́ nínú álífábẹ́ẹ̀tì èdè Gíríìkì, Ómégà sì ni lẹ́tà tó gbẹ̀yìn.