Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ẹkùn ilẹ̀ Siberia, ẹ̀yà irú ọ̀wọ́ tí ó tóbi jù lọ, lè tẹ̀wọ̀n tó 320 kìlógíráàmù, kí ó sì gùn tó mítà 4.