Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àwọn irú enzyme míràn dà bí amòfin aṣètò ìkọ̀sílẹ̀ tí ń tini sí nǹkan; iṣẹ́ wọn jẹ́ láti ya àwọn molecule nípa.