Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Gẹ́gẹ́ bí ìwé náà, The Nile, tí Emil Ludwig kọ, ti sọ, àwọn tí wọ́n jẹ́ ọmọ ibẹ̀ láyé ọjọ́un kò lè ṣàlàyé kankan nípa òjò dídì tó wà lórí òkè ńlá náà. Wọ́n tipa bẹ́ẹ̀ gbà gbọ́ pé, “ńṣe ni àwọn òkè ńlá náà fa ìtànṣán òṣùpá mọ́ra.”