Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Èrò àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórí ọ̀ràn iṣẹ́ abẹ pípààrọ̀ ẹ̀yà ara ni pé kí kálùkù ṣe ohun tí ẹ̀rí ọkàn rẹ̀ bá sọ.