Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àpilẹ̀kọ yìí ń sọ̀rọ̀ nípa irú ìjàlọ kan tó ń jẹ́ Eciton, èyí tó wà ní Àárín Gbùngbùn àti Gúúsù Amẹ́ríkà.