Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d Ìwé ìròyìn Jí! kò pọ̀n sẹ́yìn ọ̀kankan nínú àwọn èròǹgbà tó yàtọ̀ síra yìí o. Ó wulẹ̀ ń sọ nípa wọn ni.